Kọrinti Kinni 10:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ẹnìkan bá sọ fun yín pé, “A ti fi oúnjẹ yìí ṣe ìrúbọ,” ẹ má jẹ ẹ́, nítorí ẹni tí ó sọ bẹ́ẹ̀ ati nítorí ẹ̀rí-ọkàn.

Kọrinti Kinni 10

Kọrinti Kinni 10:20-29