Kọrinti Kinni 10:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kò lè mu ninu ife Oluwa tán kí ẹ tún lọ mu ninu ife ti ẹ̀mí burúkú. Ẹ kò lè jẹ ninu oúnjẹ orí tabili Oluwa, kí ẹ tún lọ jẹ ninu oúnjẹ orí tabili ẹ̀mí burúkú.

Kọrinti Kinni 10

Kọrinti Kinni 10:12-23