Kọrinti Kinni 10:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ṣé ohun tí mò ń sọ ni pé ohun tí a fi rúbọ fún oriṣa jẹ́ nǹkan? Tabi pé oriṣa jẹ́ nǹkan?

Kọrinti Kinni 10

Kọrinti Kinni 10:18-25