Kọrinti Kinni 1:8 BIBELI MIMỌ (BM)

ẹni tí yóo fi ẹsẹ̀ yín múlẹ̀ títí dé òpin, tí ẹ óo fi wà láì lẹ́gàn ní ọjọ́ ìfarahàn Oluwa wa, Jesu Kristi.

Kọrinti Kinni 1

Kọrinti Kinni 1:1-17