Kọrinti Keji 9:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí olukuluku ṣe bí ó bá ti pinnu ninu ọkàn rẹ̀, kì í ṣe pẹlu ìkanra, tabi àfipáṣe, nítorí onínúdídùn ọlọ́rẹ ni Ọlọrun fẹ́.

Kọrinti Keji 9

Kọrinti Keji 9:5-13