Kọrinti Keji 9:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí kì í ṣe àìní àwọn onigbagbọ nìkan ni iṣẹ́ ìsìn yìí yóo pèsè fún, ṣugbọn yóo mú kí ọpọlọpọ eniyan máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọrun.

Kọrinti Keji 9

Kọrinti Keji 9:2-15