Kọrinti Keji 9:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ẹni tí ó ń pèsè irúgbìn fún afunrugbin, tí ó tún ń pèsè oúnjẹ fún jíjẹ, yóo pèsè èso lọpọlọpọ fun yín, yóo sì mú kí àwọn èso iṣẹ́ àánú yín pọ̀ sí i.

Kọrinti Keji 9

Kọrinti Keji 9:8-11