Kọrinti Keji 8:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n tilẹ̀ ṣe ju bí a ti lérò lọ, nítorí pé ara wọn pàápàá ni wọ́n kọ́ gbé bùn wá, tí wọ́n sì yọ̀ǹda fún Ọlọrun nípa ìfẹ́ rẹ̀.

Kọrinti Keji 8

Kọrinti Keji 8:1-16