Kọrinti Keji 8:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí mo jẹ́rìí pé wọ́n sa ipá wọn, wọ́n tilẹ̀ ṣe tayọ agbára wọn, tìfẹ́tìfẹ́ ni wọ́n sì fi ṣe é.

Kọrinti Keji 8

Kọrinti Keji 8:1-12