Kọrinti Keji 8:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ìfẹ́ láti mú ọrẹ wá bá wà, Ọlọrun gba ohun tí eniyan bá mú wá. Ọlọrun kò bèèrè ohun tí eniyan kò ní.

Kọrinti Keji 8

Kọrinti Keji 8:9-15