Kọrinti Keji 7:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Ọlọrun tí ń tu àwọn tí ọkàn wọn bá rẹ̀wẹ̀sì ninu, ti tù wá ninu nígbà tí Titu dé.

Kọrinti Keji 7

Kọrinti Keji 7:3-15