Kọrinti Keji 7:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkàn mi balẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ yín. Mò ń fi ọwọ́ yín sọ̀yà. Mò ti ní ìtùnú kíkún. Ninu gbogbo ìpọ́njú wa, mo ní ayọ̀ lọpọlọpọ.

Kọrinti Keji 7

Kọrinti Keji 7:1-7