Kọrinti Keji 7:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Inú Titu dùn si yín lọpọlọpọ nígbà tí ó ranti bí gbogbo yín ti múra láti ṣe ohun tí ó sọ fun yín ati bí ẹ ti gbà á pẹlu ìbẹ̀rù ati ìwárìrì.

Kọrinti Keji 7

Kọrinti Keji 7:5-16