Kọrinti Keji 7:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìdí rẹ̀ nìyí tí a fi ní ìtùnú.Lẹ́yìn pé a ní ìtùnú, a tún ní ayọ̀ pupọ nígbà tí a rí bí ayọ̀ Titu ti pọ̀ tó, nítorí ọkàn rẹ̀ balẹ̀ láàrin gbogbo yín.

Kọrinti Keji 7

Kọrinti Keji 7:6-16