Kọrinti Keji 6:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ má ṣe da ara yín pọ̀ mọ́ àwọn alaigbagbọ. Nítorí ìrẹ́pọ̀ wo ni ó wà láàrin ìwà òdodo ati aiṣododo? Tabi, kí ni ó pa ìmọ́lẹ̀ ati òkùnkùn pọ̀?

Kọrinti Keji 6

Kọrinti Keji 6:5-18