Kọrinti Keji 5:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, a ní ìgboyà nígbà gbogbo. A mọ̀ pé níwọ̀n ìgbà tí a bá fi ara yìí ṣe ilé, a dàbí ẹni tí ó jáde kúrò lọ́dọ̀ Oluwa.

Kọrinti Keji 5

Kọrinti Keji 5:1-14