Kọrinti Keji 5:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, a jẹ́ aṣojú fún Kristi. Ó dàbí ẹni pé àwa ni Ọlọrun ń lò láti fi bẹ̀ yín. A fi orúkọ Kristi bẹ̀ yín, ẹ bá Ọlọrun rẹ́.

Kọrinti Keji 5

Kọrinti Keji 5:18-21