Kọrinti Keji 4:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Àkọsílẹ̀ kan sọ pé, “Mo gbàgbọ́, nítorí náà ni mo fi sọ̀rọ̀.” Nígbà tí ó ti jẹ́ pé a ní ẹ̀mí igbagbọ kan náà, àwa náà gbàgbọ́, nítorí náà ni a fi ń sọ̀rọ̀.

Kọrinti Keji 4

Kọrinti Keji 4:6-17