Kọrinti Keji 4:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé nígbà gbogbo ni à ń fi ẹ̀mí wa wéwu nítorí Jesu, níwọ̀n ìgbà tí a wà láàyè, kí ìyè Jesu lè hàn ninu ẹran-ara wa tí yóo di òkú.

Kọrinti Keji 4

Kọrinti Keji 4:2-17