Kọrinti Keji 4:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí èyí, níwọ̀n ìgbà tí ó wu Ọlọrun ninu àánú rẹ̀ láti fi iṣẹ́ yìí fún wa ṣe, ọkàn wa kò rẹ̀wẹ̀sì.

Kọrinti Keji 4

Kọrinti Keji 4:1-6