Kọrinti Keji 3:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Kì í ṣe pé a ní agbára tó ninu ara wa, tabi pé a ti lè ṣe nǹkankan fúnra wa. Ṣugbọn láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun ni a ti ní gbogbo nǹkan ní ànító.

Kọrinti Keji 3

Kọrinti Keji 3:2-11