Kọrinti Keji 3:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin alára ni ìwé wa, tí a ti kọ sí ọkàn wa. Gbogbo eniyan ni wọ́n mọ ìwé yìí, tí wọ́n sì ń kà á.

Kọrinti Keji 3

Kọrinti Keji 3:1-6