Kọrinti Keji 3:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ǹjẹ́ Oluwa tí à ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ yìí ni Ẹ̀mí Mímọ́. Níbikíbi tí Ẹ̀mí Oluwa bá wà, òmìnira wà níbẹ̀.

Kọrinti Keji 3

Kọrinti Keji 3:7-18