Kọrinti Keji 3:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn títí di ọjọ́ òní, nígbàkúùgbà tí wọn bá ń ka Òfin Mose, aṣọ a máa bo ọkàn wọn.

Kọrinti Keji 3

Kọrinti Keji 3:11-18