Kọrinti Keji 3:13 BIBELI MIMỌ (BM)

A kò dàbí Mose tí ó fi aṣọ bojú rẹ̀, kí àwọn ọmọ Israẹli má baà rí ògo ojú rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ sì ni ògo tíí ṣá ni.

Kọrinti Keji 3

Kọrinti Keji 3:8-15