Kọrinti Keji 2:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ẹ wá dáríjì í. Kí ẹ fún un ní ìwúrí. Bí ìbànújẹ́ bá tún pọ̀ lápọ̀jù kí ó má baà wó irú ẹni bẹ́ẹ̀ mọ́lẹ̀.

Kọrinti Keji 2

Kọrinti Keji 2:1-8