Kọrinti Keji 2:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ti ẹni tí ó dá ìbànújẹ́ yìí sílẹ̀, èmi kọ́ ni ó bà ninu jẹ́ rárá. Láì tan ọ̀rọ̀ náà lọ títí, bí ó ti wù kí ó mọ, gbogbo yín ni ó bà ninu jẹ́.

Kọrinti Keji 2

Kọrinti Keji 2:1-8