Kọrinti Keji 2:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Fún àwọn tí wọn ń ṣègbé, a dàbí òórùn tí n pani, ṣugbọn fún àwọn tí à ń gbàlà, a dàbí òórùn dídùn tí ó ń fún wọn ní ìyè. Ta ló tó ṣe irú iṣẹ́ yìí?

Kọrinti Keji 2

Kọrinti Keji 2:13-17