Kọrinti Keji 2:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ọkàn mi kò balẹ̀ nígbà tí n kò rí Titu arakunrin mi níbẹ̀. Mo bá dágbére fún àwọn eniyan níbẹ̀, mo lọ sí Masedonia.

Kọrinti Keji 2

Kọrinti Keji 2:7-17