Kọrinti Keji 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹ bá dáríjì ẹnikẹ́ni, èmi náà dáríjì í. Nítorí tí mo bá ti dáríjì eniyan, (bí nǹkankan bá fi ìgbà kan wà tí mo fi níláti dáríjì ẹnikẹ́ni), mo ṣe é nítorí tiyín níwájú Kristi.

Kọrinti Keji 2

Kọrinti Keji 2:1-17