Kọrinti Keji 13:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà inú wa dùn nígbà tí àwa bá jẹ́ aláìlera, tí ẹ̀yin sì jẹ́ alágbára. Èyí ni à ń gbadura fún, pé kí ẹ tún ìgbé-ayé yín ṣe.

Kọrinti Keji 13

Kọrinti Keji 13:1-13