Kọrinti Keji 12:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ gbà pé n kò ni yín lára. Ṣugbọn àwọn kan rò pé ọlọ́gbọ́n ẹ̀wẹ́ ni mí, ati pé ẹ̀tàn ni mo fi mu yín.

Kọrinti Keji 12

Kọrinti Keji 12:14-18