Kọrinti Keji 12:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀nà wo ni a fi ba yín lò tí ó burú ju ti àwọn ìjọ ìyókù lọ; àfi ti pé èmi fúnra mi kò ni yín lára? Ẹ forí jì mí fún àṣìṣe yìí!

Kọrinti Keji 12

Kọrinti Keji 12:2-21