Kọrinti Keji 12:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí èyí mo ní inú dídùn ninu àìlera mi, ati ninu àwọn ìwọ̀sí, ìṣòro, inúnibíni ati ìpọ́njú tí mo ti rí nítorí ti Kristi. Nítorí nígbà tì mo bá jẹ́ aláìlera, nígbà náà ni mo di alágbára.

Kọrinti Keji 12

Kọrinti Keji 12:7-13