Kọrinti Keji 11:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Aposteli èké ni irú àwọn bẹ́ẹ̀. Ẹlẹ́tàn ni wọ́n, tí wọn ń farahàn bí aposteli Kristi.

Kọrinti Keji 11

Kọrinti Keji 11:10-15