Kọrinti Keji 11:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Gẹ́gẹ́ bí òtítọ́ Kristi ti wà ninu mi, kò sí ohun tí yóo mú mi yipada ninu ohun tí mo fi ń ṣe ìgbéraga ní gbogbo agbègbè Akaya.

Kọrinti Keji 11

Kọrinti Keji 11:5-18