Kọrinti Keji 10:16 BIBELI MIMỌ (BM)

A óo wá mú ọ̀rọ̀ ìyìn rere kọjá ọ̀dọ̀ yín, láì ṣe ìgbéraga nípa iṣẹ́ tí ẹlòmíràn ti ṣe ní ààyè tirẹ̀.

Kọrinti Keji 10

Kọrinti Keji 10:10-18