Kọrinti Keji 1:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìrètí wa lórí yín sì ti fẹsẹ̀ múlẹ̀, nítorí tí a mọ̀ pé bí a ti jọ ń jẹ irú ìyà kan náà, bẹ́ẹ̀ náà ni a jọ ní irú ìwúrí kan náà.

Kọrinti Keji 1

Kọrinti Keji 1:2-13