Kọrinti Keji 1:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí gẹ́gẹ́ bí a ti ní ìpín ninu ọpọlọpọ ìyà Kristi, bẹ́ẹ̀ náà ni a ní ọpọlọpọ ìwúrí nípasẹ̀ Kristi.

Kọrinti Keji 1

Kọrinti Keji 1:1-11