Kọrinti Keji 1:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ti fi èdìdì rẹ̀ sí wa lára, ó tún fi Ẹ̀mí Mímọ́ ṣe onídùúró sí ọkàn wa gẹ́gẹ́ bí ẹ̀rí ohun tí yóo tún fún wa.

Kọrinti Keji 1

Kọrinti Keji 1:15-24