Kọrinti Keji 1:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Gẹ́gẹ́ bí Ọlọrun ti ṣe é gbẹ́kẹ̀lé, ọ̀rọ̀ wa pẹlu yín ti kúrò ní “bẹ́ẹ̀ ni” ati “bẹ́ẹ̀ kọ́.”

Kọrinti Keji 1

Kọrinti Keji 1:8-19