Kọrinti Keji 1:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ó dá mi lójú bẹ́ẹ̀ ni mo ṣe fẹ́ kọ́kọ́ wá sọ́dọ̀ yín, kí ayọ̀ yín lè di ìlọ́po meji.

Kọrinti Keji 1

Kọrinti Keji 1:5-24