Kọrinti Keji 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò sí ohunkohun tí a kọ si yín tí ẹ kò lè kà kí ó ye yín. Mo sì ní ìrètí pé yóo ye yín jálẹ̀.

Kọrinti Keji 1

Kọrinti Keji 1:3-18