Kọrinti Keji 1:11 BIBELI MIMỌ (BM)

bí ẹ bá ń fi adura yín ràn wá lọ́wọ́. Nígbà náà ni ọpọlọpọ eniyan yóo ṣọpẹ́ nítorí ọpọlọpọ oore tí Ọlọrun ṣe fún wa.

Kọrinti Keji 1

Kọrinti Keji 1:8-19