Kolose 4:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìkíni tí èmi Paulu fi ọwọ́ ara mi kọ nìyí. Ẹ ranti pé ninu ẹ̀wọ̀n ni mo wà.Kí oore-ọ̀fẹ́ kí ó wà pẹlu yín.

Kolose 4

Kolose 4:16-18