Kolose 3:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ọmọ, ẹ máa gbọ́ràn sí àwọn òbí yín lẹ́nu ninu ohun gbogbo, nítorí ohun tí ó wu Oluwa nìyí.

Kolose 3

Kolose 3:17-25