Kolose 3:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Boríborí gbogbo nǹkan wọnyi, ni pé kí ẹ gbé ìfẹ́ wọ̀. Ìfẹ́ ni ó so àwọn nǹkan yòókù pọ̀, tí ó sì mú wọn pé.

Kolose 3

Kolose 3:13-15