Kolose 2:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn nǹkan wọnyi yóo ṣègbé bí ẹ bá ti lò wọ́n tán. Ìlànà ati ẹ̀kọ́ eniyan ni wọ́n.

Kolose 2

Kolose 2:14-23