Kolose 2:19 BIBELI MIMỌ (BM)

kò dì mọ́ ẹni tíí ṣe orí, tí ó mú kí gbogbo ara, ati iṣan, ati ẹran-ara wà pọ̀, tí ó ń mú un dàgbà bí Ọlọrun ti fẹ́.

Kolose 2

Kolose 2:16-23