Kolose 1:4 BIBELI MIMỌ (BM)

A ti gbúròó igbagbọ yín ninu Kristi Jesu ati ìfẹ́ tí ẹ ní sí gbogbo àwọn eniyan Ọlọrun.

Kolose 1

Kolose 1:1-7